Download Mp3 “Oba Ni” Music by Tope Alabi Ft. Ty Bello
Nigerian Contemporary Christian Songer & Songwriter, Tope Alabi & Ty Bello Release New Song Titled “Oba Ni” Oba Ni Is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit.
Listen & Download Free Mp3 Audio, Stream Music Video & Lyrics. Share & Stay being blessed
We want to hear from you all
Drop your comments
Tope Alabi & Ty Bello – Oba Ni Lyrics
Kabio kosi oh Oluwa
Kabio kosi oh Jesu
Kabio kosi oh Oluwa
Kabio kosi oh Jesu
Oba ni
Lori aye gbogbo oh
Oba ni
Lori orun oh
Oba lo je
Lori ohun gbogbo to da oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Kabio osi oh Oluwa
Kabio osi oh Jesu
Kabio osi oh Oluwa
Kabio osi oh Jesu
Oba ni o
Lori aye gbogbo
Oba ni o
Lori awon orun
Oba ni o
Lori aye gbogbo oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Oba ni o
Lori aye gbogbo
Oba ni o
Lori eda gbogbo ohhh
Oba ni o
Lori aye gbogbo oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
(Oba ni o)
Oba ni o
Lori aye gbogbo
(Oba ni)
Oba ni o
(Lori orun gbogbo o)
Lori orun gbogbo o
(ehhhhhhhh)
Oba ni o
Lori aye gbogbo oh
(oba ni)
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
(One more time)
(Oba ni o
Lori aye gbogbo
Oba ni o
Lori orun gbogbo ohhh
Oba ni o
Lori aye gbogbo oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh)
Ohhhoh
Oba ni o
Lori aye gbogbo
Oba ni o
Lori orun gbogbo
Oba ni o
Lori aye gbogbo
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
(Maa sope Oba ni)
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
(Oba ni oh ohoh)
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
(Ooba no ohohoh)
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Oba ni oh, oba ni oh, oba ni oh
Patapta ola
Ololu to lu aye
Olu aye aye o dalu
Olu aye o ko aye nila
O gbe aye
Ogbee daada
Ohun gbogbo too da daradara ni
Oba ni ohhhh ehhheh oba ni oh
Ariro ala
Oba tin gbe nipekun orun
Gbegbeleku to nda nibi to hun
Iwo to ni gbogbo eemi eniyan pata
Ellemi to mi so wa, to daa si wa, to fifun wa
Oba ni ohhhh ohhhoh
Back up:Oba ni oh
Oba ni ohhhh ohhhoh
Back up:Oba ni oh
Haa oba ni ohhhh ohhhoh
Back up:Oba ni oh
Igbengbaye
Egan o ran pepe
Ani para inu ola
Alabiye obiye obayeye borun ye bisale ile
Talabafi O we? Ta lo Le ba O dogba
Gonboki oro gonboki ede
Eni to ni gbogbo ipa ati agbara lowo ohhhohoh
Iwo nikan lemi O ma ki ti hunoma ki
Huno ki o koja ologun eru ma ki O koja oniwefa ogbon
Ogbongbon ologbongbon ogbon gbon
Iwo nikan lo ni
Ola ogbon bi ogbon kogbon daagba fi ogbon fun ni
Oloogbonla oh
Eni ti gbogbo ohun toon da nrubo fun
Ogo Ogo Ogo ogo
Ehhheh Oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
Oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
(maa gbe owow re soke , maa yin
Maa sope Ogo ni fun Oluwa)
Oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
He is king of kings
Oba ni oh oh oh ohhh
Back up:Oba ni oh
He is Lord of Lords
Oba ni oh oh oh ohhhh
Back up:Oba ni oh
Oba ni, oba ni, oba ni oh ohhhohoh
Back up:Oba ni oh
(Tongues)
Iwo to joko ni gbungbun orun
Ton seun to hun o
Olumori, moju, momu, mopa, moti, mo gbogbo ara
Iwo to je koja ekan laarin ero koja inukukun ninu kunkun awon orun
Ipendaye Kabiyesi Olorun oba oh
Talabafiowe talolebaodogba
Egbo tani? Tani a le fi se ikeji e
Talale sope ko duro, o duro, o dabi tohun, o lagbara bi tohun
Kabio osi oh oba ni oh
Kabio osi oh oba ni oh
Haa oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
Haa oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
There is nobody like him ohhhhohohh
Back up:Oba ni oh
Oba ni oba ni ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
Agbe o ga latisale inu wa wa
A juba re Olorun
Awa ti an dagban yin oh
A o dabi awon ti won kin looosu, looto
Iwo nikan ni won ki ti won juba fun lojojo aye tiwan
Awon yen o laaye orun nikan looni won den fi orun won bo Olorun
(Tongues)
Awon eda too da siwaju re ti won yi itee ka
Iwo nikan ni won ki ti won dobale fun lojojo
Orun ti kin ka ojo, orun ti kin ka osu
Orun ti kin ka dun tin ka igba kankan
Ti o nigba ti o lojo
Tabi aba sowipe maa daake maa panude ni ojo kan
Won fo ojojumo, ojojumo ti o lojumo ti o lojo, to o nigba
Ti ale o yato si owuro
Ti owuro o yato si osan
Osan o yato si iyaleta
Iyaleta o yato si aji oru
(Kabiyesi oh)
Won gbe oo ga, won gbe ooga
Wonn gbe oo ga , won yin o logo oh
Gbogbo orun kanfata
Won yin o logo
Ite re ti o losuwon, ti o lodiwon, ni won fogo fun
Oju ogo re tin dan gbirin to ohun lonn fogo fun
Iwo tonn fi ojojokojo aye orun tuntun nene naakojojo fun
Kabiyesi tuntun nene, funfun nene, kenene funfun
Ologbo ori, tutun funfun didan pinpin wura
Ibaleba oh Ibaleba oh
Baba baba
Oba ni ohohhhhohoh
Back up:Oba ni oh
Oba ni o oh ko seni to fi o je
Back up:Oba ni oh
Eh ehheh Oba ni o oh ko seni to fi o soye
Back up:Oba ni oh
Aoo gbe o lope bi kasope e jawe afogofun
Back up:Oba ni oh
Koseni to sowipe o daa loye eje a fije oh
Back up:Oba ni oh
Awa wole ajuba fun oba wa
Back up:Oba ni oh
Awa wole ajuba fun oba wa
Back up:Oba ni oh
Eyin eyan e wole ejuba fun oba
Back up:Oba ni oh
Eda gbo gbo wole e sope fun oba wa
Back up:Oba ni oh
Ehhheh ee wole ejuba fun oba
Oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
Oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
Oba ni ohhhh ohhhoh Oba ni oh
Back up:Oba ni oh
Tope Alabi & Ty Bello – Oba Ni Music Video
The post [Music] Tope Alabi & Ty Bello – Oba Ni appeared first on Mp3smash.